Image

Grandma Said Lyrics by ATS


ATS Lyrics

Lyrics of Grandma Said by ATS center on a grandmother’s heartfelt blessings, prayers, and words of wisdom for a loved one. The message emphasizes long life, peace, prosperity, and staying connected to family and faith.

Cover art for ATANDA SOUNDS album by ATSCover art for ATANDA SOUNDS album by ATS
ATANDA SOUNDS Album Cover Art

ATS – Grandma Lyrics

Sálamu Aláyíkùn ooo
Ọkọ′ mi Àtàndá, ẹ kú ọjọ’ mẹ′ta ooo
Ẹ’ẹ’ ní dámù; Ọlọ́hun ò gbéyìn ga o
Ẹ̀mí gígùn, àlàáfíà Ọlọ́hun ò fì tayin lọ′rẹ o
Ṣẹ′kẹ’rẹ′ owó Ọlọ́hun ò dà léyìn lọ́wọ́ o
Ẹ’ẹ′ ní gbé ìyàwó oníyàwó; ìyàwó tiyín lẹ ó gbé o

Ìyàwó àlùbáríkà
Lọ́lá Ànọ́bì Muhammad
(sallallahu alayhi wa sallam)
Ẹ’ẹ′ ti yé wá bẹ’rẹ’ wá, ẹ′hẹ′n?
Ó tó ọjọ́ mẹ’ta
Mo ṣáà n jàran é, jàran é, jàran é, jàran é títí ni!
Bí Ọlọ́hun ṣe wá ni, èmi àti mámà yín àti àbúrò rẹ
A jọ pàdé níbí lónìí

Ó wá dùn mọ′ mi púpọ’
Bí mo tiyẹ′ ṣe gbọ́ ohùn rẹ yìí
Wàláhì, ó dùn mọ’ mi, ó dùn mọ′ mi púpọ’!
Ẹ̀mí rẹ ó wá gùn lógo Ọlọ́hun
O ò ní ríkú tó yàwó
O ò ní pa ara mọ’ ayé lára
Ẹ̀mí gígùn, àlàáfíà, ìgbélé ayé gbádùn ìròrùn
Ọlọ́hun ó jọgun e fún ọ
Ẹ kú iṣẹ′ ooo!

Ẹ kú iṣẹ′, àmọ’ ìwọ náà máa rántí mi oo
Kóo dígbà tá a bá kú tán kè tó máa wá fi kúrisì rántí wa
Máa rántí mi ooo!
Gbogbo ìgbà ni èmi máa ń jàran é
Kódà bí mo ṣe gbúrọ́ rẹ lónìí, ó tún dùn mọ′ mi púpọ’
Ayò mi tún lẹ′kùn
Ìdùnnú mi tún pọ̀ sí!
Kóo wá dá kún, torí Ọlọ́hun, ẹ máa ti gbàgbé wa bá yí
Àìtíkú ayé náà la ṣì wà
Ẹ má ti gbàgbé wa

Ẹ ó rílẹ’ rẹ wò lógo Ọlọ́hun
Ìyàwó àlùbáríkà, ọmọ àlùbáríkà Ọlọ́hun ó fì tayin lọ′rẹ
Ẹ’ẹ’ ní dámù, ẹ′ẹ′ ní pa ara mọ’ ayé lára o
Lọ́lá Ànọ́bì Muhammad, Lọ́lá Ìláfí
Bismillahi Rahmani Rohim
Lí-ííláfí Quráíṣin Íláfíhim ríhlatá sh-shítá-í wa ṣ-ṣóíf
Fál-yá′búdúú rábba háadhál báýt
Al-ladhíi aṭámáhúm min jûúín wa áamanáhúm min khóúf

Àmín mẹ’ta mẹ′ta
Àmíìn, Àmíìn, Àmíìn
Síṣowa ò kú
Ríri wa ò kú
Lágbára Ọlọ́hun
Ọlọ́hun ó sì jẹ’ ká ṣì wà lóke yẹ′pẹ’
Lọ́lá Ànọ́bì Muhammad (sallallahu alayhi wa sallam)
Aaní dámù o!

Check Lyrics of latest songs here, and get fresh updates as they drop via X and Facebook





Source link

Releated Posts

Amu The Principal Honours Pro Kid With Nostalgic Tribute To “Heads & Tales”

Amu The Principal Honours Pro Kid With Nostalgic Tribute To “Heads & Tales.” Producer and artist Amu The…

ByByNews on SantoshHub Jul 15, 2026

Roiii & Loatinover Pounds Fuel Anticipation Over Upcoming Collaboration

Roiii & Loatinover Pounds Fuel Anticipation Over Upcoming Collaboration. South African hip hop fans have another collaboration to…

ByByNews on SantoshHub Jul 15, 2026

K.O Scores Streaming Milestone With ‘Hotela’

K.O Scores Streaming Milestone With ‘Hotela.’ K.O is celebrating another major achievement after his latest single, “Hotela,” featuring…

ByByNews on SantoshHub Jul 15, 2026

Jay Jody Reveals The Honest Inspiration Behind His Verse On Touchline’s “Not That Guy Anymore”

Jay Jody Reveals The Honest Inspiration Behind His Verse On Touchline’s “Not That Guy Anymore.” Jay Jody has…

ByByNews on SantoshHub Jul 15, 2026

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top